Welcome to our Yoruba list of the most popular words and expressions. If you memorize the whole vocabulary below, you will be able to communicate with most people in Afrikaas without many issues. Make sure you add this list to your must read pages so that you don't forget the words.
Coffee kofi |
Milk wara |
Breakfast ounje aaro |
Lunch ounje osan |
Dinner ounje ale |
Bread buredi |
Cheese wara-kasi |
Chicken Ẹran adìẹ |
Eggs Àwọn ẹyin |
Fish eja |
Food Àwọn Onjẹ |
Fruit Àwọn Eso |
Meat eran |
Sandwich sanwiṣi |
Sugar Iyọ̀ òyìnbó |
Tea Tíì |
Tomatoes tomati |
Vegetables |
Water Omi |
Belt igbadi |
Clothes Awon Aso |
Coat ewu awoleke |
Dress Ẹ̀wù |
Glasses Àwọn ife ìmumi |
Gloves Ìbọ̀wọ́ |
Hat Ate/Fila |
Jacket ewu awoleke |
Pants (Trousers) sokoto |
Ring Òrùka |
Shirt ewu penpe |
Shoes bata |
Socks ibose |
Suit suutu |
Sweater ewu otutu |
Tie tai |
Umbrella Agboòrùn |
Underwear awotele |
Wallet Ọ̀pọ́ọ̀ |
Watch Aago ọ̀wọ́ |
Do you like my dress? Ṣé aṣọ mi wù ẹ́? |
Book iwe |
Books awon iwe |
Chair aga ijoko |
Desk Àpótí ìkọ̀wé |
Dictionary iwe itumo oro |
Languages awon édé |
Library ile ikojopo-iwe |
Laptop Ẹ̀rọ́ a-yára-bí-à-alá-gbé-létan |
Page oju ewe |
Paper takada |
Pen kalamu |
Question ibeere |
School Ilé Ìwé |
Student Akẹ́kọ̀ọ́ |
Teacher oluko |
University Yunifasiti |
I have a question Mo ní ìbéèrè kan |
What's the name of that book? Kínni orúkọ ìwé yẹn? |
Arm Apá |
Back Ẹ̀yìn |
Ear eti |
Eye oju |
Face oju |
Feet atelese |
Fingers Awon ika owo |
Hair irun |
Hand owo |
Head ori |
Heart okan |
Leg ẹsẹ |
Mouth ẹnu |
Neck Ọrùn |
Nose imu |
Teeth Ẹ̀yin |
She has beautiful eyes Ojú rẹ̀ rẹwà |
Airplane oko baalu |
Airport papa baalu |
Bus oko ero |
Bus station ilé ìwọ́kọ̀ bọ́ọsì |
Car oko-ayokele |
Flight Ìgbérasọ |
Help Desk Ojúkò Ìrànlọ́wọ́ |
Hotel Ilé ìtura |
Passport iwe ifuni-laaye |
Taxi oko aje-igboro |
Ticket iwe afiwole |
Tourism Ìrìnàjo afẹ́ |
Train (noun) oko oju irin |
Train station Ìbùdó ọkọ̀ ojú irin |
By train Nípa ọkọ̀ ojú irin |
By car Nípa ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ |
By bus Nípa ọkọ bọ́ọ̀sì |
By taxi Nípa ọkọ̀ ajé ìgboro |
By airplane Nípa ọkọ̀ òfúrufú |
Do you accept credit cards? Ṣe ẹ ngba kẹdirit kadi? |
How much will it cost? Eélòó ni yóò náni? |
I have a reservation Mo ti gbà ààyè sílẹ̀ |
I'd like to rent a car Mó fẹ́ láti yá ọkọ̀ |
I'm here on business /on vacation. Iṣẹ́ ló gbé mi débí/ lẹ́nu ìsinmi. |
Is this seat taken? Ṣé ẹnìkan ti gbà ìjókòó yìí? |
Good luck! [Ẹ/O] ó ṣoríire! |
Happy birthday! [Ẹ/O] kú ọjọ́ ìbí! |
Happy new year! [Ẹ/O] kú ọdún tuntun! |
Merry Christmas! [Ẹ/O] kú ọdún Kérésìmesì! |
Baby Ọmọ ọwọ́ |
Boy omokunrin |
Brother aburo/ẹgbọn ọkunrin |
Child (female) Ọmọ (abo) |
Child (male) Ọmọ (akọ) |
Cousin (female) arabirin |
Cousin (male) arakunrin |
Daughter Ọmọbìnrin |
Father baba |
Girl omobirin |
Grandfather baba-baba |
Grandmother iya-iya |
Husband Ọkọ |
Man ọkunrin |
Mother iya |
People Àwọn Eniyan |
Sister egbon/aburo obirin |
Son omokunrin |
Wife iyawo |
Woman obinrin |
How old is your sister? Báwo ni arábìnrin rẹ ti dàgbà tó |
What's your brother called? Orúkọ wo ni a npè arákùnrin rẹ? |
Actor akitọ |
Actress akirẹsi |
Artist Oníṣẹ́ ọnà/Oníṣọ̀nà |
Businessman Oníṣòwò |
Doctor onisegun |
Nurse Nọọsi |
Policeman Ọlọ́pàá |
Singer Akọrin/Olórin |
Student Akẹ́kọ̀ọ́ |
Teacher oluko |
Translator Atumọ̀ èdè/Gbédè-gbẹ́yọ̀ |
He is a policeman Ọlọ́pàá ni òun |
I'm an artist Oníṣẹ́ ọnà/Oníṣọ̀nà ni mí |
I'm looking for a job Mo nwá iṣẹ́ |
Days Àwọn ọjọ́ |
Monday ojo-aje |
Tuesday ojo-isegun |
Wednesday Ọjọ́'rùú |
Thursday Ọjọ́'bọ |
Friday ojo-eti |
Saturday ojo abameta |
Sunday ojo aiku |
January Ṣẹ́rẹ́ |
February Èrele |
March Ẹrẹ́nà |
April Igbe |
May Èbìbí |
June Òkúdù |
July Agẹmọ |
August Ògún |
September Ọ̀wẹwẹ̀ |
October Ọ̀wàrà |
November Bélú |
December Ọpẹ́ |
Autumn Ìgbà Ọyẹ |
Winter Ìgbà Òtútù |
Spring Ìgbà Afẹ́rẹ́ |
Summer Ìgbà Ooru |
Time Àkókò |
Hour Wákàtí |
Minute Ìṣẹ́jú |
Second ekeji |
I was born in July A bí mi nínú Oṣù Agẹmọ/Oṣù Keje |
I will visit you in August Ng ó bẹ̀ [ọ́/yín] wò nínú [Oṣù Ògún/Oṣù Kẹjọ] |
Cold otutu |
Hot gbona |
Rain Òjò |
Snow yin-yin |
Spring afẹrẹ |
Summer Ìgbà ooru |
Sun Oòrùn |
Sunny Oòrùn mú |
Warm lo wooro |
Wind afefe |
Windy igba afefe |
Winter Ìgbà òtútù |
It is raining Òjò nrọ̀ |
It is sunny Oòrùn mú |
It is windy Atẹ́gùn nfẹ́ |
It's cold Ó tutù |
It's hot Ó gbóná |
Bed ibusun |
Bedroom iyewu |
Computer Ẹ̀rọ a-yára-bí àṣá |
Door Ilẹ̀kùn |
Furniture Àkójọpọ̀ àga àti tábìlì |
House ile |
Kitchen ile-idana |
Refrigerator Ẹ̀rọ amónjẹ tutù |
Room Iyàrá |
Television Ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán |
Toilet ile-igbonse |
Window ferese |
Can you open the window? Njẹ́ [ẹ/o] lè ti fèrèsé? |
I need to use the computer Mo fẹ́́ lò ẹ̀rọ a-yára-bí àṣá |
Arabic Èdè Lárúbáwá |
Moroccan Morokan |
Morocco Moroko |
Chinese (language) Ṣínkó |
Chinese (nationality) Ṣainiṣi |
China Ṣaina |
English geesi |
British Gẹẹsi |
Britain Orílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì |
American Amerikan |
America Amerika |
French (language) faranse |
French (nationality) Faranse |
France Faranse |
Italian (language) italia |
Italian (nationality) Italian |
Italy Orílẹ̀-èdè Itali |
Japanese (language) japanis |
Japanese (nationality) Japanis |
Japan Orílẹ̀-èdè Japaani |
Russian (language) roshian |
Russian (nationality) Roṣiani |
Russia roshia |
Spanish (language) spanish |
Spanish (nationality) Supaniṣi |
Spain Orílẹ̀-èdé Speeni |
I don't speak Korean Mi ko le sọ ede Koreani. |
I speak Italian Mo nsọ italia. |
I want to go to Germany Mo fẹ́ lọ sí Jamani |
I was born in Italy Itali ni a bí mi sí |
Black Dúdú |
Blue Àwọ̀ Ojú Ọ̀run |
Brown Àwọ̀ igi |
Colors Àwọn Àwọ̀ |
Green Àwọ̀ Ewé |
Orange Àwọ̀ Òféfèé |
Red pupa |
White funfun |
Yellow pupa rusurusu |
I have black hair Mo ní irun dúdú |
Your cat is white Ológbò rẹ funfun |
Far Jìnnà |
Here Ìhín |
Left Òsì |
Right Ọ̀tún |
Near nitosi |
Straight Tààrà |
There Ọ̀hún |
Can I help you? Njẹ́ mo lè ràn ọ́ lọ́wọ́? |
Can you help me? Njẹ́ o lè ràn mí lọ́wọ́? |
Can you show me? Ṣé ẹ lè fi hàn mi? |
Come with me! [Ẹ] tẹ̀lé mi! |
I'm lost Mo ti ṣìnà |
I'm not from here Ìhín kọ́ ni mo ti wá |
Turn left Yà sí òsì |
Turn right Yà sí ọ̀tún |
Can you take less? Ṣẹ́ ẹ lè dín owó rẹ̀? |
Do you accept credit cards? Ṣe ẹ ngba kẹdirit kadi? |
How much is this? Eélòó ni wọ́n ntà èyí? |
I'm just looking Mo sá nwòye |
Only cash please! Owó sísan nìkan ni, ẹ jọ̀wọ́! |
This is very expensive Èyí/ Eléyìí ti wọ́n jù |
I'm vegetarian Èmi kìí jẹran |
It is very delicious! Ó dùn jọjọ! |
May we have the check please? Ẹ jọ̀wọ́, ṣé ẹ lè fún wa ní ṣẹ́ẹ̀ki náà? |
The bill please! Ẹ jọ̀wọ́, iwé owó náà! |
Waiter / waitress! weta |
What do you recommend? (to eat) Kínni ẹ fọwọ́ sí? (láti jẹ) |
What's the name of this dish? Kínni orúkọ onjẹ yìí? |
Menu Àkọsílẹ̀ |
Spoon Ṣíbí |
No problem! Kò séwu |
Accident Jàmbá |
Ambulance oko ile iwosan |
Doctor onisegun |
Headache efori |
Heart attack Àìsàn ọkàn |
Help me [Ẹ] ràn mí lọ́wọ́ |
Hospital ile iwosan |
Medicines oogun |
Pharmacy pipo-oogun |
Poison majele |
Police Ọ̀lọ́pàá |
Stomach ache inu-rirun |
Are you okay? se ara ya? |
Call a doctor! Pè oníṣègùn òyìnbó |
Call the ambulance! pe oko ile-iwosan |
Call the police! Pè ọlọ́pàá |
Calm down! Fara balẹ̀! |
I feel sick Ara mi kò dá |
It hurts here Ibí yìí npani lára |
It's urgent! Ó nfẹ́ ìkánjú |
Stop! Dúró! |
Thief! Olè! |
Animal Ẹranko |
Cat ologbo |
Dog aja |
Horse esin |
Do you have any animals? Sé ẹ/o ní àwọn ẹranko? |
I have a dog Mo ní ajá kan |
Small Kékeré |
Big Nlá |
Tall Gíga |
Short Kúkúrú |
Cheap Ó gbọ̀pọ̀ |
Expensive Ó wọ́n |
Good Dára |
Bad Kò dára |
Wrong Kò tọ̀nà/Kò tọ́nà/Kò bójúmu |
Right (correct) Tọ̀nà/Tọ́nà/Bójúmu |
New Tuntun |
Old (opposite of new) Gbó/Ti àtijọ́ |
Young Jẹ́ ọ̀dọ́ |
Old (opposite of young) Darúgbó |
Difficult Nira/Ṣòro/Le |
Easy Rọrùn |
This is too expensive Èyí wọ́n púpọ̀ jù |
Am I right or wrong? Ṣé mo tọ̀nà àbí mi ò tọ̀nà? |
Here ibi |
There ibẹyẹn |
Quickly Kíákíá |
Really lotitọ |
Slowly Díẹ̀díẹ̀ |
Always igbagbogbo |
Never ko si rara |
Sometimes lẹnkankan |
Next week Ọ̀sẹ̀ tí ó nbọ̀ |
Now Ìsisìyí |
Soon Láìpẹ́ |
Today oni |
Tomorrow ola |
Tonight ale yi |
Yesterday ana |
Do you like it here? Njẹ́ [ẹ/o] fẹ́ bí ó ti rí níhín? |
See you later! Ó dìgbà kan ná! |
Thank you very much! [Ẹ/O] ṣe púpọ̀! |
Woman Obìnrin |
Women awon arabirin |
Man Ọkùnrin |
Men awon ọkunrin |
Boy Ọmọdékùnrin |
Boys awon omokunrin |
Girl Ọmọdébìnrin |
Girls awon omobirin |
Country ìlú |
Countries Awọ́n Orílẹ̀ Èdè |
We speak two languages Mo so ede meji. |
Cat ologbo |
Dog aja |
Woman obinrin |
Women awon arabirin |
Mother mama |
Sister aburo/ẹgbọn obirin |
I have a dog Mo ní ajá kan |
I speak Italian Mo nsọ italia. |
A French teacher is here Olukọ faranse kan wa nihin. |
The French teacher is here Olukọ faranse na wa nihin. |
Some languages are hard Awọn ede kan le. |
Many languages are easy Awọn ede pupọ le. |
The student speaks Korean Akẹkọ na sọ ede korean. |
A student speaks Korean Akẹkọ kan sọ ede korean. |
Some students speak Korean Awọn akẹkọ kan sọ ede korean. |
In front of niwaju |
Behind lehin |
Before saaju |
After lehin |
Inside ninu |
With pelu |
Without laisi |
Outside ita |
On top of ori rẹ |
Under nisale |
And ati |
Between laarin |
But sugbon |
For fun |
From lati |
In inu |
Near Súnmọ́ |
Or abi |
Can I practice Italian with you? Ṣe mo le puratisi ede itali pẹlu rẹ. |
I speak French but with an accent Mo nsọ faranse, sugbọn pẹlu ami. |
Boy ọmọkunrin |
Girl ọmọbinrin |
Man ọkunrin |
Woman Obìnrin |
Father baba |
Mother iya |
Brother egbon/aburo okunrin |
Sister egbon/aburo obirin |
Cat (Masc.) ologbo |
Cat (Fem.) ologbo |
He is tall O o ga. |
She is tall O o ga. |
He is a short man ọkunrin kukuru ni. |
She is a short woman Obinrin kukuru ni. |
One ẹyokan |
Two meji |
Three meta |
Four merin |
Five marun |
Six mefa |
Seven meje |
Eight mejo |
Nine mesan |
Ten mewa |
I emi |
You iwo |
He oun |
She oun |
We awa |
You (plural) eyin |
They awon |
I love you Mo nífẹ̀ẹ́ [rẹ/yín] |
Me mi |
You iwo |
Him un |
Her un |
Us wa |
You (plural) ẹyin |
Them won |
Give me your phone number Fun mi ni nọmba ibanisọrọ rẹ. |
I can give you my email Mo le fun ẹ ni imeeli mi. |
My mi |
Your re |
His tire |
Her tire |
Our wa |
Your (plural) tiwọn |
Their won |
His email is … Imeeli rẹ ni ... |
My phone number is … Nọmba mi ni ... |
How? Báwo? |
What? Kínni? |
When? Nígbà wo? |
Where? Níbo? |
Who? Tani? |
Why? Kí ló fà á? |
Can I help you? Njẹ́ mo lè ràn ọ́ lọ́wọ́? |
Can you help me? Njẹ́ o lè ràn mí lọ́wọ́? |
Do you speak English? Njẹ [ẹ/o] nsọ èdè Gẹ̀ẹ́sì? |
How much is this? Eélòó ni wọ́n ntà èyí? |
What is your name? Kini orukọ rẹ? |
What time is it? Àkókò wo ni?/ Aago mélòó?/ Kínni aago sọ? |
When can we meet? Ni gbawo ni a ma rira? |
Where do you live? Ibo ni [ẹ/o] ngbé? |
Who is knocking at the door? Tani o nka ilẹkun? |
Why is it expensive? Kini o ṣe wọn? |
No oti |
Nothing kosi |
Not yet koiya |
No one ko si enikan |
No longer Ko si mọ |
Never rara |
Cannot ko le ṣe |
Should not kò gbọdọ̀ |
Don't worry! Má ṣe ìyọnu! |
I cannot remember the word Mi ko ranti oro na. |
I do not speak Japanese Mí ko sọ́ Japani. |
I don't know! Mi ò mọ̀! |
I'm not fluent in Italian yet Mi ko le sọ italian jaara. |
No one here speaks Greek Ko si ẹni ti o nsọ giriki nihin. |
No problem! Kò séwu |
To drive Láti wakọ̀ |
To drive wà |
To give fún |
To have ní |
To know mọ |
To understand yé |
To work ṣiṣẹ́ |
To write kọ́ |
He understands me Ọ̀rọ̀ mí ye e. |
He understood me Ọ̀rọ̀ mí ti ye e. |
He will understand me Ọ̀rọ̀ mí ma ye e. |
I see you Mo rí ẹ. |
He reads a book Ó ka ìwé. |
He understands me Ọ̀rọ̀ mí ye e. |
She has a cat Ó ní ológbò. |
She knows my friend Ó mọ òrẹ́ mi. |
We want to learn A fẹ́ kọ́. |
We think Spanish is easy Á rò pé Súpániṣi rọrùn. |
They drive a car Nwọn nwa ọ́kọ̀ ayọ́kọlẹ. |
They smile Nwọn rẹ́rìn. |
I saw you Mo tí rí ẹ. |
I wrote with a pen Mo tí kọ́ pẹ̀lú kálàmù. |
You loved apples Ó tí fẹ́ràn ápùlù. |
You gave money Ó tí fun ní owó. |
You played tennis Ó ti ṣeré tẹnísì. |
He understood me Ọ̀rọ̀ mí ti ye e. |
She had a cat Ó ti ní ológbò. |
She knew my friend Ó ti mọ òrẹ́ mi. |
We wanted to learn A ti fẹ́ kọ́. |
They smiled Nwọn ti rẹ́rìn. |
I will see you Mo ma rí ẹ. |
I will write with a pen Mo ma kọ́ pẹ̀lú kálàmù. |
He will read a book Ó ma ká ìwé. |
He will understand me Ọ̀rọ̀ mí ma ye e. |
We will think about you A ma ronu nipa rẹ. |
Go! Lọ! |
Stop! Dúró! |
Don't Go! Ma lọ! |
Stay! Duro! |
Come here! Wa nibi! |
Be quiet! Dakẹ! |
Go straight Lọ tààrà |
Wait! Duro! |
Let's go! Jẹ kalọ! |
Sit down! Joko! |
Good Dára |
Better dara ju |
Best dara julọ |
Bad Kò dára |
Worse bajẹ ju |
Worst bajẹ julọ |
Taller ga ju |
Shorter kuru |
Younger kere ju |
Older da gba ju |
As tall as ga bi |
Taller than ga ju |
Shorter than kuru ju |
More beautiful dara ju |
Less beautiful dara diẹ |
Most beautiful dara pupo |
Happy Inú rẹ̀ dùn |
Happier idunu pupọ |
Happiest idunu pupọ pupọ |
You are happy Inu rẹ dun. |
You are as happy as Maya Inu rẹ dun bi Maya. |
You are happier than Maya Inu rẹ dun ju Maya. |
You are the happiest Iwọ ni inu rẹ dun ju. |
Hi! Báwo! |
Good morning! [Ẹ/O] káárọ̀! |
Good afternoon! [Ẹ/O] káàsán! |
Good evening! [Ẹ/O] kú ìrọ̀lẹ́!, [Ẹ/O] kú alẹ́! |
How are you? (polite) Ṣé dáadáa ni? |
How are you? (friendly) Báwo ni? |
What's up? (colloquial) Kí ló nṣẹlẹ̀? |
I'm fine, thank you! Mo wà dáadáa, [ẹ/o] ṣeun! |
And you? (polite) [Ìwọ/Ẹ̀yin] náa nkọ́? |
And you? (friendly) [Ìwọ/Ẹ̀yin] náa nkọ́? |
Good Dára |
Do you speak English? Njẹ [ẹ/o] nsọ èdè Gẹ̀ẹ́sì? |
Just a little Díẹ̀ ṣá |
What's your name? Kínni orúkọ [rẹ/yín]? |
My name is (John Doe) Orúkọ mi ni (John Doe) |
Mr.../ Mrs. .../ Miss... Ọ̀gbẹ́ni…/Aya…/Omidan |
Nice to meet you! Ó dára láti rí [yín/ọ]! |
You're very kind! [Ẹ/O] ní inú rere púpọ̀! |
Where are you from? Níbo ni [ẹ/o] ti wá? |
I'm from the U.S Ilẹ̀ Amẹrika ni mo ti wá |
I'm American Ọmọ ilẹ̀ Amẹrika ni mí |
Where do you live? Ibo ni [ẹ/o] ngbé? |
I live in the U.S Ilẹ Amẹrika ni mo ngbé |
Do you like it here? Njẹ́ [ẹ/o] fẹ́ bí ó ti rí níhín? |
How old are you? Ọmọ ọdún mélòó ni [ọ́/yín]? |
I'm (twenty, thirty...) Years old Ọmọ (oguń, ọgbọ̀n….) ọdún ni mi |
Are you married? Ṣé o/ẹ ti ṣe ìgbéyàwó? |
Do you have children? Ṣé [ẹ/o] ní àwọn ọmọ |
I have to go Mo ní láti lọ |
I will be right back! Mà á padà wá! |
Nice to meet you! Ó dára láti rí [yín/ọ]! |
Can I practice Italian with you? Ṣe mo le puratisi ede itali pẹlu rẹ. |
My French is bad Èdè Faranse mi kò dára |
I need to practice my French Mo ní láti máa ṣe àgbéyèwò èdè Faranse mi |
Would you like to go for a walk? Àbí [ẹ/ọ] ó rìn jáde lọ? |
Can I have your phone number? Ṣé [ẹ/o] lè fún mi ní nọ́mbà ẹ̀rọ ìbániṣọ̀rọ̀ [yín/rẹ]̀? |
Can I have your email? Ṣé [ẹ/o] lè fún mi ní ímeèlì yín/rẹ |
Are you married? Ṣé [ẹ/o] ti ṣe ìgbeyàwó? |
I'm single Mi ò tíì ṣe ìgbeyàwó |
Are you free tomorrow evening? Ṣé wàá ráàyè ní ìrọ̀lẹ́ ọ̀la? |
I would like to invite you for dinner Mo nfẹ́ láti pè [ọ́/yín] síbi àsè |
Where do you live? Ibo ni [ẹ/o] ngbé? |
When can we meet? Ni gbawo ni a ma rira? |
Do you like it? Ṣé [ẹ/o] fẹ́ ẹ? |
I really like it! Mo fẹ́ ẹ nítòótọ́! |
I love you Mo nífẹ̀ẹ́ [rẹ/yín] |
Would you marry me? Ṣé [ẹ/o] ó fẹ́ mi? |
I hope you enjoyed this lesson about the most used phrases and vocabulary in Yoruba. Please check out our main menu here for more lessons: homepage. Now check the next lesson below.
Inspirational Quote: A coward gets scared and quits. A hero gets scared, but still goes on. |